Ihooho Victoria ti Adewale loo yoju wo l`Oshodi ti ko o si wahala

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Ihooho Victoria ti Adewale loo yoju wo l'Oshodi ti ko o si wahala
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Ijoba tuntun:
Ileesôeô oôloôpaa ti taari oôkunrin eôni oôdun meôrindinlogoji kan, Azeez Adewale, loô sile-eôjoô
majisreeti to wa ni Igbeôhinadun,l'Oshodi. Arale eô to n weô to loôoô yoôju wo ni baluweô lo ko o si
wahala.
Geôgeô bi agbeônusoô ileesôeô oôloôpaa, Inspeôkitoô Keôhinde O·latunde, sôe sôalaye, oôseô to lo loôhun-un
ni afurasi oôhun to n gbe laduugbo Arowojoôbeô, l'Oshodi, l'Ekoo, sôeô eôsôeô naa, o loôoô yoôju wo
araale eô kan, Victoria Emmanuel, ni baluweô to ti n weô.
O ni nisôe loôkunrin naa jokoo si oôoôdeô ile woôn nigba ti arabinrin yii gbe koroba omi lati loôoô
weô, nigba to si ri i pe iyeôn gboôna ileeweô lo yoô teôle e, to si doôgboôn loôoô duro seôyin ibeô, beôeô lo n
doôgboôn yoôju wo o nibi iho kan to wa nibi baluweô oôhun. Sôadeede lo ni Victoria fura pe
eônikan n wo oun, eyi lo si mu ko da omi oôsôeô si i loju. Leôyin eyi lo ni Azeez ja woôle, to si
beôreô si i ko eôsôeô bo o loju, ko too di pe iyeôn pariwo pe awoôn eeyan lati ran an loôwoô, awoôn
araale yii lo si gba a loôwoô eô.
Sôiwaju akoko yii lo ni afurasi yii ti loôoô kanleôkun eôni yii leôeômeji oôtoôoôtoô loru oôganjoô to loun
nisôeô toun feôeô jeô fun un. O·latunde ni nisôe lo maa n beôbeô pe kiyeôn sôileôkun nitori pe oôreô reô kan
lo ran oun si i sôugboôn ti obinrin naa ki i da a loun, ohun to maa n soô ni pe ko jeô kileô oôjoô keji
moô.
Eôsôeô yii ni Inspeôkitoô naa lo tako abala meji kan ninu iwe ofin ipinleô Eko toôdun2011, to si
nijiya ninu.
Niwoôn igba ti afurasi yii ti loun ko jeôbi, Adajoô Akeem Fashoôla pasôeô pe ki woôn gba beeli eô
peôlu eôgbeôrun loôna aadoôta naira ati oniduuro kan. O sun igbeôjoô si oôjoô keôjoô, osôu keôfa, oôdun yii
Muhammadu Buhari ti
bere ise o
Ife owo lo koba egbe
oselu PDP—Seneto
Ogunwale
Eyi ni bi owo olopaa se
te adigunjale nibi
igbeyawo e
Onarebu to n lu awon
eeyan ni jibiti ha sowo
olopaa n’Ibadan
Funmilayo gun omo e
lobe pa l'Ota, won ni
baba e lo bi omo naa
fun
Nitori rogbodiyan
Ekiti, Fayose sepade
bonkele pelu awon
asofin APC l'Akure
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa