Iya Biola Oniresi Loja Osodi Seki nibo lo wa, awon ebi ti muyawo mi

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Iya Biola Oniresi Loja Osodi
Seki nibo lo wa, awon ebi ti muyawo mi-in wa fun baba e o
Ki i sôe bi Seôki sôe soôroô eô lo ri jare, oôtoô loun to sôeôleô, ohun to sôeôleô kan tun kamama ju ti teôleô
loô ni. Ki i sôe pe emi ni awoôn eôbi Alaaji waa ba ja, Alaaji funra eô ni, awoôn ni woôn joô n fa oôroô
naa moô ara woôn leônu, ko tileô si eyi to kan mi nibeô rara. Sôugboôn gbogbo eô naa ni mo kuku
gboô, inu yara mi ni mo wa ti Boôoôda Tade, oôkan ninu awoôn alateônujeô aburo Alaaji yeôn ti waa
tu gbogbo eô fun mi, o si tun soô fun mi pe ki n ma soô fun eôni kankan o, iru oôroô beôeô yeôn ko le
maa loô ki oun ma soô fun mi ni. Emi naa ti soô fun un pe ko si bi mo sôe le soô oô, oôroô awo ni.
Ki woôn too sôepade lo ti waa ba mi, o ni oun feôeô ba mi soôroô oômoô oun kan toun feô ko waa
koôsôeô loôdoô mi, ko maa boô ni sôoôoôbu mi ko maa ba mi taja, to ba si ti moô oôn daadaa, oun n
gbero lati fun un lowo ko loôoô da tieô sileô. Ni mo ba soô fun un pe sôe iyeôn lo sôeôsôeô wa n tori eô ri
mi si, mo ni ta lo ni sôoôoôbu, ta lo mi emi to ni in, sôebi oun naa ni, bo jeô loôla lo feôeô mu oômoô eô
wa ko maa boô, O·loôrun kuku si sôe e, ile baba eô wa ti yoo maa gbe, mo ni ko kan soô fun boôoôda
eô pe oun n mu oômoô oun boô loôdoô mi ni, mo ni bo ba ti soô beôeô, ko da eyi to ku da mi.
Bo sôe soô yeôn tan, mo ro pe inu eô to dun lo fa a, bo sôe beôreô si i jaboô niyeôn. Lo ba ni oun ko
tieô feôeô wa si ipade tawoôn waa sôe naa, o ni Baba Agba lo ni afi ki oun teôle woôn nitori oôroô to sôe
pataki tawoôn feôeô waa ba boôoôda oun soô, iyeôn Alaaji. Nigba to si ti soô beôeô, ko ma da bii pe emi
naa ko wi kinni kan, ni mo ba ni sôe ko sôaa si laburu sôa, o ni ko si laburu, ko si laburu. Mo ni
sôe ki i sôe pe wahala ti tun sôeôleô lori oôroô ileô famili woôn, o tun ni rara, beôeô lo n sôeôju koôikoôi, ni
mo ba ni abi eô ti ri iyawo kekere fun boôoôda yin, sôeô eô moô pe eô ti n soô oô tipeô.
Bi mo sôe soô iyeôn lo ba n feôgbeô kan eônu reôrin-in, loootoô kuku si ni, woôn ti n soô oô tipeô, woôn ti n
sôalaye eô tipeô laarin ara woôn, woôn ni awoôn ko feô bi boôoôda awoôn sôe n feô awoôn iyawo lati Eko,
woôn ni oômoôde kan lo yeô ko feô lati abule awoôn, bo deô jeô Abeôokuta lo ti maa mu un, woôn ni
iyeôn a le gboôroô si i leônu daadaa, ibi to ba si fi i si, ibeô ni iyeôn yoo jokoo si, woôn ni gbogbo
awoôn iyawo eô lo ti dagba, awoôn oômoô woôn ti n bimoô nile oôkoô, woôn ko roju raaye toôju eô moô,
asiko to yeô ko feô oômoô kekere niyi, ki i kuku sôe pe ko lowo ti yoo fi boô oô.
Ni gbogbo igba ti woôn ba ti rojoô beôeô, ti woôn tun soô oô kan mi loju, eôrin ni emi maa n rin ni
temi, n ko jeô soô pe ko daa, sôe ki n soô fun woôn pe oômoô woôn ko lowo ti yoo fi boô iyawo ki woôn
ni mo n sôepe fun un, abi ki woôn ni mo n puroô, ki woôn ni nitori n ko feô ki iyawo mi-in woôle
lara sôe n kan mi beôeô. Sôe emi moô, Alaaji funra eô si moô pe eônikeôni to ba n wa iyawo foun loôwoô
toun wa yii, ko sôe daadaa foun, ko feôran oun, nitori nigbeôyin, woôn yoo kan fi da wahala soun
loôrun ni.
Nitori eô lo sôe jeô pe gbogbo igba ti woôn ba ti soôroô iyawo kekere, nisôe ni mo maa n soô fun woôn
pe ori mi gbe e, aya mi gba a, ko maa boô, ile wa fun un. Eyi ti a si wa n soô ti Boôoôda Tade n
foju reôrin-in bii obinrin yii, o da bii pe o ti sôeôleô niyeôn. Ni mo ba tun soô fun Boôoôda yeôn, mo
ni, “Eôrin leô n rin ni, sôe o ti sôeôleô ni ka le moô ibi ti a ti maa loôoô mu iyawo wa o, nitori lasiko
yii, n ko ni i feô ko jeô eôyin leô tun maa loôoô ba mi mu iyawo wale, mo feô loôoô mu un funra mi ni,
nitori emi ni mo sôaa feôeô gba iyawo.’’
Bi mo sôe soô beôeô yeôn, nisôe ni Boôoôda Tade sare foôwoô bo mi leônu, o ni ki n ma jeô ki oôroô ti mo n
soô yeôn jade sita, lemi naa ba sinmi. O le to beôeô yeôn ni! Nigba yeôn lo waa sôalaye pe oôroô yeôn
ko ri beôeô, ki i sôe oôroô to sôee maa soô beôeô, nitori awoôn ko ti i moô boya oôkoô wa maa gba tabi ko
ni i gba, nitori gbogbo eôbi ti soô pe ohun tawoôn feô ko sôe niyeôn, sôugboôn ko ma waa di pe aa ni
oun ko ni i sôe beôeô, iyeôn ni gbogbo awoôn sôe wa. Mo ni ewo ni eôbeô ninu eô pe ki eôgboôn yin
feôyawo kekere, nigba ti gbogbo eôbi ti foôwoô si i.
Boôoôda Tade ni ki i sôe iyawo kekere beôeô, o ni agbalagba ni, sôugboôn ki i sôe agbalagba beôeô naa,
dieô lo maa fi ju mi loô, oun ati Iya Dele ni woôn maa joô jeô eôgbeô. Ni mo ba mi kanleô, nnkan de.
Boôoôda Tade ba roôra deô ohun sisaleô patapata, lo ba n sôalaye loô. O ni sôe mo ranti boôoôda awoôn
to wa ni Ghana, mo ni mo ranti daadaa, Baba Ghana, mo ni ki lo de, o ti peô ti woôn ti wale,
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
O tan, PDP ipinle Oyo
da Akinjide, Adeseun
duro
Egbe PDP ile Yoruba
yari, won ni Muazu
gbodo fipo re sile
Nitori gbese to je, Sifu
Difensi lu pasito
lalubami l’Ondo
Owo te iya agbalagba
to jale loja Kuto
l'Abeokuta
E ba wa farada iya yii
fosu kan to ku—APC
Osun
Omo odun meji ni
Bidemi ba lo po l'Agege
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa
boya ni ko ti le ni oôdun meôeôeôdogun bayii ti emi ti ri woôn. Boôoôda Tade ni beôeô ni, o ni o di oôdun mejidinlogun
ti woôn ti wale gbeôyin. Ni mo ba ni sôe woôn ti pada de ni!
Ni Boôoôda Tade ba ni ki i sôe beôeô, woôn ti ku ni! Ni mo ba ni haa, awa o ma gboô. O ni woôn ti ku si Ghana lati
bii osôu meôfa seôyin, ko si seôni to gboô afi igba tiyawo eô atawoôn oômoô woôn meji ti ko ti i dagba pupoô, ti woôn
keôru de, ti woôn ni baba awoôn ti ku. Woôn ni Baba Agba faraya, gbogbo eeyan lo binu, afi igba to sôalaye pe
Anti Agbekeô, iyeôn oômoô eôgboôn woôn kan bayii to jeô Ghana niyeôn n gbe lati kekere, to si ti koôle sibeô, lo ni ki
woôn sin in soôhun-un, woôn ni Agbekeô si ti koôkoô soôroô naa fun woôn lori foonu ko too di pe awoôn iyawo pada de
yii.
Nibi ti oôroô sôaa ti waa kan awa bayii ni pe woôn ni woôn ti wo oôtun, woôn ti wo osi, eôni kan naa ti woôn ro o pe o
le sôupo obinrin yii ni oôkoô wa, woôn ni oun nikan lo le gbe bukaata eô to si le toôju awoôn oômoô reô, ti yoo si maa
sôe oôkoô eô. Ohun ti gbogbo eôbi sôe wa niyeôn, woôn ni awoôn feô ki Alaaji waa sôupo iyawo Baba Ghana. Bo sôe n
soôroô yeôn ni woôn sare pe e, mo n gbo, ‘Baba Moôrufa, Taade, lo ba sare dide, o ni ipade ti beôreô.
Bo sôe jade ni mo pa ileôkun mi de gbaga, inu eô ti bi mi. Awoôn onirinkunrin agbalagba, awoôn ki i ri nnkan
daadaa kan pe aburo woôn si afi oôroô obinrin sôaa ni! Seôki nibo lo wa, Seôki maa boô o, woôn ni ki baba eô waa
sôupo!