E ba wa dele E mo nipa wa ba wa sise Adiresi wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Fijilante yinbon pa Adamu niluu Kaiama, o ti dero ogba ewon Bi o ba fe Awon Iroyin to se koko Ibo ku si dede: PDP O ·kunrin fijilante kan, Saidu Haruna, to n gbe labule Kini-Kini, lagbegbe Kaiama, nipinleô Kwara, loôwoô awoôn oôloôpaa ti teô pe o yinboôn pa Adamu Lawal, woôn si ti woô oô loô sile-eôjoô. O·woô teô Saidu laipeô yii, leôyin ti oôkunrin Fulani kan toun naa n gbe labule kan naa, Sanni Lawal, fisôeôleô oôhun to ileesôeô oôloôpaa ipinleô Kwara leti. O feôsun kan oôkunrin eôni oôdun marundinlaaadoôta oôhun pe o yinboôn pa Adamu ti i sôe aburo reô lai nidii kan. Geôgeô bi alaye Sanni, ija kan lo sôeôleô ninu osôu keôsan-an, oôdun 2014, laarin awoôn iyawo aburo reô meji kan, Adamu Lawal to ti doloogbe bayii ati iyawo Shehu Lawal, awoôn si gbe eôjoô loô soôdoô olori abule naa ti woôn pe ni Sarki Kango, Isiaka Gandi. Iyeôn lo da oloogbe naa leôbi, o si pasôeô pe ko sanwo itanran ti i sôe eôgbeôrun loôna oôgoôrin naira (80,000). O sôalaye pe nigba ti oloogbe naa ko ri owo oôhun san lo fi abule oôhun sileô peôlu gbogbo moôleôbi reô. Sôugboôn nigba to di oôjoô keôtadinlogun, osôu keôwaa, oôdun 2014 lawoôn sôadeede ri Adamu to pada wa si abule. Loôjoô naa, ni nnkan bii aago meôwaa aaroô ni Adamu woôlu wa lati gbe oôkada reô to fi sileô lasiko to n ko loô, nibi to ti n tun oôkada naa sôe lawoôn fijilante ti ri i, ti woôn si gbiyanju lati mu un, sôugboôn o feôseô feô eô. Saidu ni woôn soô pe o gba teôle oloogbe naa to si yinboôn fun un, loju-eôseô ni Adamu naleô to si ku fin-in fin-in. Iwe eôsun tawoôn oôloôpaa fi gbe afurasi oôhun wa sile-eôjoô fi han pe olujeôjoô oôhun jeôbi eôsun didana iboôn ya oloogbe naa lai nidii kan, ati pe leôyin to pa a tan lo na papa bora ko too di pe oôwoô teô eô loôjoô kejilelogun, osôu kejila, oôdun 2014. O·loôpaa to sôoju ijoôba, Koôburu Cornelius Adebayoô, soô fun ile-eôjoô pe iwadii sôi n loô loôwoô lori eôsun ti woôn fi kan afurasi naa. O tako gbigba oniduuro olujeôjoô oôhun, o si roô adajoô lati fi afurasi naa pamoô si ahamoô oôgba eôwoôn titi teôjoô oôhun yoo fi pari. Adajoô M. A Ndakene pasôeô pe ki woôn loôoô fi olujeôjoô pamoô soôgba eôwoôn to wa l'Oke-Kura, niluu Iloôrin, o si sun eôjoô oôhun ipinle Ogun ko ti i mo ibi ti won n lo Omoose gomina lu osise abe re lalubami l'Ondo PDP nikan lo le mu ayipada rere ba ipinle Kwara—Ajibola Mimiko yoo je ki PDP fidi remi nipinle Ondo—Olu Ogunye Ibo gomina: Ajimobi pe Ladoja, Akala si iforowero ita gbangba Agbaboolu Afrika: Ta ni yoo di oba? E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa
© Copyright 2024 ExpyDoc